Text:Ojo Nla L'ojo Ti Mo Yan
Author:Philip Doddridge
Translator:Anonymous
Tune:O HAPPY DAY
Composer:Anonymous
Composer (refrain):Edward Rimbault
Media:MIDI file

15903. Ojo Nla L'ojo Ti Mo Yan

1 Ojo nla l’ojo ti mo yan
Olugbala l’Olorun mi;
O ye ki okan mi ma yo,
K’o si ro ihin na ka ‘le.

Egbe:
Ojo nla l’ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu
O ko mi ki nma gbadura
Ki nma sora ki nsi ma yo
Ojo nla l’ojo na!
Ti Jesu we ese mi nu.

2 Ise igbala pari na,
Mo di t’Oluwa mi loni;
On l’o pe mi ti mo si je,
Mo f’ayo jipe mimo na. [Egbe]

3 Eje mimo yi ni mo je
F’enit ’o ye lati feran;
Je k’orin didun kun ’le Re,
Nigba mo ba nlo sin nibe. [Egbe]

4 Simi, aiduro okan mi,
Simi le Jesu Oluwa;
Tani je wipe aiye dun
Ju odo awon angeli? [Egbe]

5 Enyin orun gbo eje mi;
Eje mi ni ojojumo,
Em’o ma so dotun titi
Iku y’o fi mu mi re ’le. [Egbe]

Text Information
First Line: Ojo nla l’ojo ti mo yan
Title: Ojo Nla L'ojo Ti Mo Yan
English Title: O happy day that fixed my choice
Author: Philip Doddridge
Translator: Anonymous
Refrain First Line: Ojo nla l’ojo na!
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: O HAPPY DAY
Composer: Anonymous
Composer (refrain): Edward Rimbault
Key: F Major or modal
Copyright: Public Domain



Media
Adobe Acrobat image: PDF
MIDI file: MIDI
Noteworthy Composer score: Noteworthy Composer Score
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us